Ojú Kálé: Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Sọ̀rọ̀ Nípa Ètò Ẹ̀yáwó Akẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Ìjọba Àti Owó Ilé-ìwé Tó Gbẹ́nu Sókè
A bá àwọn ará ìlú sọ̀rọ̀ nípa ọ̀rọ̀ ètò ẹ̀yáwó akẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ ìjọba láti kàwé nílé-ìwé ìjọba. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló bẹnu àtẹ́ lu ìgbésẹ̀ yìí pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdí. Àwọn ará ìlú tún mẹ́nu ba ọ̀rọ̀ owó ilé-ìwé tó gbé pẹ́ẹ́lí sí i ní àwọn ilé-ìwé ìjọba kan, wọ́n sì ràwọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba kí wọ́n
Read More
